Ònkọ̀wé aya ọba

Ònkọ̀wé aya ọba Ibí yìí wà fún ìtan aládùn kíkà ti yorùbá

09/04/2025

Ekaaro gbogbo ile,ojumo Ire ni oni yii yoo je fun wa. Amin.

Ekaaro gbogbo ile,aku ojumo,oni a san wa oo.Amin.Bi ase ti mo pe Odun Ajinde Jesu ati Odun itunu awe n sun mole,mo ni ki...
27/03/2025

Ekaaro gbogbo ile,aku ojumo,oni a san wa oo.Amin.
Bi ase ti mo pe Odun Ajinde Jesu ati Odun itunu awe n sun mole,mo ni ki n polowo ohun ti emi aburo yin,omo yin Onkowe Aya Oba n ta fun yin.
Ibiti mo ti n rowo mu lo enu re,awa la n se, be si ni awa la n to.
Se Adire le fe ni
Se Batiki ni
Se jakadi ni
Ko si a*o ti awa ko le ya ise si lara.
Ale ya ise si ori Sifon(chifon),gini(guinea),kirepu(Crep) ati bebelo.
Anfaani wa fun eyin ti e fe ra ara tun ta ati fun awa ti a fe ra fun wiwo.
E gba mi laago tabi ki e bami soro lori wasapu.
Eseun pupo pupo.

Address

Onihale
2903

Telephone

+2348128366520

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ònkọ̀wé aya ọba posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Organization

Send a message to Ònkọ̀wé aya ọba:

Share

Category