06/10/2014
AKOKO NAA TOO GE TI AWON OMO OKEIGBO MA FI OPIN SI IYANIJE INU ETO ISELU.KAAKIRI AWON IPINLE TI O KO ARA JO PO NJE NAIJIRIA.NI ETO A NPIN IPO OSELU LAARIN AWON AGBEGBE TI O KO ARA JO PO NJE KONSITUENSI.E WA SE JE TI,TI IPINLE ONDO YOO WA FI DA YATO.LATI ODUN 1999 TI A TI BERE ETO OSELU ELEKERIN NI IJOBA NAIJIRIA,EKUN IJOBA APAPO TI A NPE NI ILEOLUJI/OKEIGBO/ODIGBO FED.CONST. TI N FI ETO ILU OKEIGBO DU;KODA WON KO JE KI ILU OKEIGBO MU ALAGA IJOBA IBILE JADE, KI A TO MA WA SO TI ILE IGBIMO ASOJU S'OFIN; SUGBON NI BAYI ORO OJOGBON OLOGBE OBAFEMI AWOLOWO TI WA TO MU LO.NI EYITI O SO PE OWO ENI NI A FI NJA FUN ETO ENI; http://yo.m.wikipedia.org/wiki/Obafemi_Awolowo AWA OMO OKEIGBO ORI NI WA LATI IBERE,NINU IJOBA IPINLE TI A MO SI ONDO NI ODE ONI YI.KO SI ILU KAN TI O LE SO WIPE AWON SIWAJU NI GBAJUMO TIWON MO KA AGBAYE; OLOGBE OLOOYE D.O.FAGUNWA TI O JE OMO YORUBA AKO'KO TI O MA SE IWE AKAGBADUN LITIRESO JADE, SEBI ILU OKEIGBO NI WON TI BI.O GBAJUMO DE ILU GEESI;O TUN GBOYE M.B.E. WA SILE. DELE ODUWALE RE O!E GBA