01/02/2025
Èkìtì kete A ku oríire. Ìjọba BAO n' se bebe.
Yàra lọ sí www.blc.ekitistate.gov.ng. láti jẹ ànfààní àti rí iṣẹ́ kontirati gbà lọdọ ìjọba. Ànfààní yìí wà fún gbogbo onírúurú oníṣẹ́ ọwọ́, alákọ̀wé, kọngilá paapa jùlọ àwọn tó fẹ gba iṣẹ kontirati.
Fún ìbéèrè ati alààyè, pe EKSBOLC sórí 09160003661 tabi ki o lo sì ilé iṣẹ wọn ni, Governor's Office, Ado-Ekiti, Ekiti State.
Mase fi àkókò ṣòfò —kan si www.blc.ekitistate.gov.ng lóòní.