27/08/2026
Eku ojumo ni ikanni ayelujara igbalode yii gbogbo awa ololufe eto atpo ati alejo ni ikanni Ajilete fm 92.1 Gambari Ogbomoso monfi asiko yii sofunwa wipe eto atpo yo o gberaso ni oni ojobo (Thursday)ni deede agogo marun abo irole 5:30pm,eto toni yoo tun dun yato.eti tefi ngbowa konidii loruko Jesu.Omo yin,Ololufa yin naa ni Peteru omo baba tisa.